Lyrics
Intro
Oluwa tobi ni Sioni
(God is great in Zion)
O si joba lori gbogbo orile-ede
(He reigns over all nations)
Je ki won yin oruko re ti o tobi, ti o si leru
(Let them praise His name, for it is great and full of awe)
Oh, my God
Call and Response 1
Lead: Gbogbo aye n wariri ni oruko re, won nkorin
(The whole world is trembling at the mention of His name; they are singing)
Response: E ti tobi to, Jesu
(You are great, Jesus)
Lead: Awon orun n seleri, won foribale niwaju ite re, won so wipe
(The heavens are declaring, prostrating before His throne, saying)
Response: E ti tobi to, Jesu
(You are great, Jesus)
Lead: Won ni, “E ti tobi to,” oh, oh, oh, Oluwa
(They say You are great, oh Lord)
Response: E ti tobi to, Jesu
(You are great, Jesus)
Lead: Won ni, “E ti tobi to,” oh, oh, oh, oh, Oluwa wa
(They say You are great, oh Lord, our Lord)
Response: E ti tobi to, Jesu
(You are great, Jesus)
Declaration 1
Lead: Awon oke nla nla won foribale o, tori iwo ni ogo ati ola ju oke nla ikogun won ni lo o
(The great mountains are prostrating, for You are greater in glory and honor, greater than the mighty mountains)
Response: E ti tobi to, Jesu
(You are great, Jesus)
Lead: Iwo ti Olorun ji dide ninu oku lati gba wa kuro ninu ibinu ti n bo o
(You, the Lord God, who rose from the dead to save us from impending wrath)
Response: E ti tobi to, Jesu
(You are great, Jesus)
Lead: Iwo Oluwa Olorun to n gbe larin awon kerubu, to po ni ipa ati agbara o
(You, Lord God, who dwells among the cherubim, full of power and might)
Response: E ti tobi to, Jesu
(You are great, Jesus)
Call and Response 2
Lead: Ani gbogbo aye n wariri ni oruko re, won nkorin, yee
(Indeed, the whole world trembles at His name; they are singing)
Response: E ti tobi to, Jesu
(You are great, Jesus)
Lead: Awon orun n seleri, won foribale niwaju ite re
(The heavens declare, prostrating before His throne)
Response: E ti tobi to, Jesu
(You are great, Jesus)
Lead: E ti tobi to, oh, oh, oh, oh, Oluwa wa
(You are great, oh Lord our Lord)
Response: E ti tobi to, Jesu
(You are great, Jesus)
Declaration 2
Lead: Ipekun ola, ipekun iye, ye, eh, eh, eh, E ti tobi to, oh, oh, oh, oh
(Endless glory, endless life; oh yes, You are great)
Response: E ti tobi, Jesu
(You are great, Jesus)
Lead: Ireti wa o, eri wa o, oh, oh, oh, E ti tobi to, oh, oh, oh
(Our hope, our reward; You are great)
Response: E ti tobi to, Jesu
(You are great, Jesus)
Lead: Itan sho to wole, ro, ro, ro, ro, ro; E ti tobi to, aye ati orun n bo o
(The story comes; the world and heaven tremble)
Response: Won n juba; E ti tobi to, Jesu; won foribale
(They worship; You are great, Jesus; they prostrate)
Biblical Declaration
Lead: Jordani ri o, o pada seyin; okun ri o, o sa. E ti tobi to, Olodumare
(The Jordan saw Him and turned back; the sea saw Him and parted. You are great, Almighty God)
Response: E ti tobi to, Jesu
(You are great, Jesus)
Lead: Abetilukarabiajere, Baba mi, agba oye; E ti tobi to, oh, oh, oh, oh, oh
(Great in power, my Father; You are great)
Response: E ti tobi, Jesu
(You are great, Jesus)
Call and Response 3
Lead: Tori na, gbogbo aye n wariri ni oruko re, won nkorin
(For the whole world trembles at His name; they sing)
Response: E ti tobi to, Jesu
(You are great, Jesus)
Lead: Awon orun n seleri, won foribale niwaju ite re, eh, eh, eh
(The heavens declare, prostrating before His throne)
Response: E ti tobi to, Jesu
(You are great, Jesus)
Lead: Won ni, “E ti tobi to,” oh, oh, oh, Oluwa wa
(They say You are great, oh Lord our Lord)
Response: E ti tobi to, Jesu
(You are great, Jesus)
Lead: Gbogbo idile Jesse, Jesu, won nkorin, foribale, won so wipe
(The entire house of Jesse sings and prostrates, saying)
Response: E ti tobi to, Jesu
(You are great, Jesus)
Declaration 3
Lead: Ipekun ola, ipekun oro, ipekun agbara; E ti tobi to, E ti tobi to, oh, oh, oh, oh, oh
(Endless glory, endless word, endless power; You are great)
Response: E ti tobi to, Jesu
(You are great, Jesus)
Lead: Ore ati ola nla ni o wa ni iwaju re; ipa ati ewa n be ni ibi mimo re
(Great power and glory are before You; strength and beauty are in Your holy place)
Response: E ti tobi to, Jesu
(You are great, Jesus)
Lead: Aiikakatan o, aiibubutan o, atobi loye, ongbe leyin eni a n da loro o; E ti, E ti, E ti tobi to
(There is none like You, none greater; You are great)
Response: E ti tobi to, Jesu
(You are great, Jesus)
Final Call and Response
Lead: Jesu, gbogbo aye n wariri ni oruko re, won nkorin
(Jesus, the whole world trembles at His name; they sing)
Response: E ti tobi to, Jesu
(You are great, Jesus)
Lead: Awon orun n seleri, won foribale niwaju ite re, oh, eh
(The heavens declare, prostrating before His throne)
Response: E ti tobi to, Jesu
(You are great, Jesus)
Worship Bridge
Won juba fun Ajunilo o
E ba n juba f'Ajunilo eh
E ba n seba f'Ajunilo o
E ba gbo'suba f'Ajunilo
E ba n gbo osuba f'Ajunilo o
E ba n kira f'Ajunilo o
E ba n juba f'Ajunilo o
E ba mi juba f'Ajunilo
E ba n gbo'suba f'Ajunilo o
E ba n seba f'Ajunilo o
(They worship the Savior; let us worship the Savior, sing for the Savior, and call upon the Savior)
Final Refrain
Lead: Ani gbogbo aye n wariri ni oruko re, won nkorin
(Indeed, the whole world trembles at His name; they sing)
Response: E ti tobi to, Jesu
(You are great, Jesus)
Outro
Oh, my God
Credits & Song Information
- Performed By
- EmmaOMG featuring Pelumi Deborah, BBO & The OhEmGee Choir
- Official source verified · Apple Music
- Writer
- Bakare Boluwatife Oluwatobi, Emmanuel Edunjobi, Pelumi Deborah
- Official source verified · Apple Music
Video
Meaning & Inspiration
EmmaOMG’s “E Ti Tobi to (Great Are You)” keeps returning to a single declaration: Jesus is great. Yet the repetition does not feel thin; it becomes the point. The lyrics gather creation’s testimony—the earth trembling at His name, heavens bowing before the throne, mountains prostrating—and set it beside redemptive history. The reference to Jordan turning back and the sea parting echoes the psalmist’s language of nature responding to God’s presence, while the line about rising from the dead to save from impending wrath grounds that majesty in salvation. There is also a striking blend of transcendence and nearness: God dwells among the cherubim, yet is called “our hope” and “our reward.” The song’s closing phrases, “endless glory, endless word, endless power,” extend the greatness beyond any single act. The response line functions like a congregational confession, each stanza adding another reason while the answer remains the same. That steady refrain shapes an entire world where all praise converges on Jesus alone.